Recent Scheme of Work on Yoruba Language

Syllabus for Middle Basic

FIRST TERM
BASIC 4 BASIC 5 BASIC 6
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 2

Theme: EdeÌ

Topic: Ònka lati ogorun-un de igba (100 - 200)

Sub-Topic:
Content:
1. ònka lati ogorun-un de igba
2. Àròpọ̀ ati ayọkúrò awon ònka kan ti yoo fun wa ni ònka miiran b.a. (20 x 7 = ogoje – 10 = aadoje 130).
3. Titoka si awon oro to se pataki fun ònka (le ati din).
4. Sise àròpọ̀ ati ayọkúrò pelu awon ònka naa.
WEEK 2

Theme: EdeÌ

Topic: Ònka lati ogorun-un de igba(200-300)

Sub-Topic:
Content:
1. ònka Yorubá lati igba deOodunrun
2. Alaye kikun nipa ònka:Ogun méjìla = ojilenigba= 20x12 = 240
Ogun metala =otalenigba = 20x13 = 260
Orinlelugba = (20x14) =280
Le ni...din ni...
3. Àròpọ̀ ati ayọkúrò pelu awonònka naa.
WEEK 2

Theme: Ede

Topic: Agboye

Sub-Topic:
Content:
Oro sìso/ijiroro lori orisirisi koko oro nipa awon oro to n lo/isele awujo b.a
- iwa omoluabi
- itoju ayika eni
- ija esin
- ijoba alagbada dara ju ijoba onikaki lo
- abbl
WEEK 3

Theme: EdeÌ

Topic: Aroso

Sub-Topic:
Content:
1. Oluko yoo yan ori oro fun aroso b.a. díndín ewu inu ile ku.
2. So iru ewu to le wa ninu ile b.a. fifi obe tabi abefẹ́lé ge owo; yiyo subu; omi/epo gbigbóná dida jóni abbl.
3. Salaye bi a se le din in ku/dena an re: itoju ti a le fun eni to fara pa ninu ile b.a igbese kiakia nipa lilo ero ibani-soro lati pe fun iranlowo, gbígbé lo si ile iwosan, dida eje eni ti o ba farapa abbl.
WEEK 3

Theme: EdeÌ

Topic: Agboye

Sub-Topic:
Content:
1. Oluko le mu ori oro to je moalaye sise b.a. ounje ti moferan ju, oja ilù mi, abbl.
2. Isoro ati ìdáhùn.
3. Ibeere lati mo pe akekoo gboohun ti oluko so ni agboye
WEEK 3

Theme: Ede

Topic: Gbolohun alakanpo

Sub-Topic:
Content:
1. ihun gbolohun alakanpo
2. Kika gbolohun alakanpo
3. Siseda gbolohun alakanpo
4. Títò ká si gbolohun alakanpo ninu àyoka nipa fifala si nidii ati kika a jade.
WEEK 4

Theme: EdeÌ

Topic: Akaye

Sub-Topic:
Content:
1. Yiyan ayoká fun kika lori koko bii oko owo aṣèjèrè abbl.
2. Kika ayoká naa ni akaye.
3. Salaye bi a se le se owo ni asejere.
4. Alaye oro ti o ta koko/tuntun.
5. Ibeere ati ìdáhùn lori ayoká.
WEEK 4

Theme: EdeÌ

Topic: Gbolohun alábọ́ dé

Sub-Topic:
Content:
1. Gbolohun alábọ́ dé jegbolohun to ni olùwa kan atioro ise kan b.a.:Olu lo, igiwo, Mo sun ni ana
2. Awon oro ise bii, wa, sun,dide, abbl le da duro gege biigbolohun alábọ́dé ti a ba lowon bii gbolohun ase.
WEEK 4

Theme: Ede

Topic: Gbolohun alakanpo (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. ihun gbolohun alakanpo
2. Kika gbolohun alakanpo
3. Siseda gbolohun alakanpo
4. Títò ká si gbolohun alakanpo ninu àyoka nipa fifala si nidii ati kika a jade.
WEEK 5

Theme: EdeÌ

Topic: Aroko

Sub-Topic:
Content:
1. Orisiirisii aroko b.a. alalaye, oniroyin, alapejuwe, abbl.
2. Aroso lori orisiirisii ohun elo ba.
- Inu ile
- Ile eko
- Aarin ilu
3. Àdàkọ awon koko oro inu aroko.
4. Aroko kiko nipa titelé ilapa ero ti oluko se.
WEEK 5

Theme: EdeÌ

Topic: Akaye

Sub-Topic:
Content:
1. Ìtẹ̀ síwájú ninu akaye.
2. Kika àyoka to ni owe atiakánlo ede.
3. Siso ero àtinúdá lori koko oroto jẹyọ ninu akaye.
WEEK 5

Theme: Ede

Topic: Onka oodunrun de eedegbeta (300 - 500)

Sub-Topic:
Content:
Onka lati odunrun de edegbeta (300-500)
WEEK 6

Theme: EdeÌ

Topic: Ifaara si leta kiko

Sub-Topic:
Content:
1. Orisiirisii leta
2. Ilapa ero leta gbefe ato aigbagbefe:
- Àdíréẹ̀sì
- Déètì
- Ìkini
- Akole
- Akoonu leta ni sise n tele
- Asokagba
- Bíbu owo lu
- Oruko.
WEEK 6

Theme: EdeÌ

Topic: Leta gbefe

Sub-Topic:
Content:
1. Ilapa ero leta gbefe.
2. Apeere leta gbefe
WEEK 6

Theme: Ede

Topic: Akaye

Sub-Topic:
Content:
1. Kika asayan ayoka lori koko oro tio je mo oro to n lo lawajo
2. Didahun ibeere ninu ayoka.
WEEK 7

Theme: EdeÌ

Topic: Ifaara si leta kiko (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Orisiirisii leta
2. Ilapa ero leta gbefe ato aigbagbefe:
- Àdíréẹ̀sì
- Déètì
- Ìkini
- Akole
- Akoonu leta ni sise n tele
- Asokagba
- Bíbu owo lu
- Oruko.
WEEK 7

Theme: EdeÌ

Topic: Pontueson siwaju si i

Sub-Topic:
Content:
Orisiirisii ami pontueson b.a.
- Ami (:), (;)
- Idanuuduro (.)
- Idanuuduro die(,)
- Ibeere (?)
- Iyanu (!)
- Ayolo (“ “)
- Ikamo (), abbl.
WEEK 7

Theme: Ede

Topic: Akaye (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Kika asayan ayoka lori koko oro tio je mo oro to n lo lawajo
2. Didahun ibeere ninu ayoka.
WEEK 8

Theme: EdeÌ

Topic: Pontueson

Sub-Topic:
Content:
Orisiirisii ami pontueson b.a. - Ami idánudúró (.)
- Idánudúró die (,)
- Ami iyanu (!)
- Ami ibeere (?)
- abbl
WEEK 8

Theme: EdeÌ

Topic: Aroko

Sub-Topic:
Content:
1. Orisiirisii aroko b.a.: alalaye,onítan, alapejuwe, abbl.
2. Salaye bi a se n ko arokoalalaye b.a.:
- Ifaara
- Ilapa ero
- Aarin
- Títò koko ni sise n tele
- Apeere orisiirisii ori oroto je mo aroko alalaye.
3. Dari akekoo lati dan ara wonipa kiko aroko alalaye.
WEEK 8

Theme: Ede

Topic: Kiko leta aigbagbefe

Sub-Topic:
Content:
1. Ohun ti leta aigbagbefe je.
2. Ko ilana leta aigbagbefe
- Adiresi
- Déètì
- Ikini
- mo
- Oro inu leta tia pin si ege ototo
- Asokagba/igunle
- Bibu owo lu oruko
WEEK 9

Theme: EdeÌ

Topic: Pontueson (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Orisiirisii ami pontueson b.a. - Ami idánudúró (.)
- Idánudúró die (,)
- Ami iyanu (!)
- Ami ibeere (?)
- abbl
WEEK 9

Theme: EdeÌ

Topic: Aroko (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Orisiirisii aroko b.a.: alalaye,onítan, alapejuwe, abbl.
2. Salaye bi a se n ko arokoalalaye b.a.:
- Ifaara
- Ilapa ero
- Aarin
- Títò koko ni sise n tele
- Apeere orisiirisii ori oroto je mo aroko alalaye.
3. Dari akekoo lati dan ara wonipa kiko aroko alalaye.
WEEK 9

Theme: Ede

Topic: Itesiwaju ninu aroko: Alariyanjiyan

Sub-Topic:
Content:
1. Ohun ti aroko alariyanjiyan je
2. Ilapa ero/ilana aroko alariyanjiyan
- Akole
- Ifaara
- Akoonu aroko tia ge si ipin otototi o si ṣàfihàn oju mejeeji ti ori oro/akole ni
- Agbalogbabo
- Kiko aroko alariyanjiyan
3. kiko aroko alariyanjiyan

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

We provide educational resources/materials, curriculum guide, syllabus, scheme of work, lesson note & plan, waec, jamb, O-level & advance level GCE lessons/tutorial classes, on various topics, subjects, career, disciplines & department etc. for all the Class of Learners

SECOND TERM
BASIC 4 BASIC 5 BASIC 6
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 2

Theme: Litireso

Topic: Ere onítan keekeeke Ere onítan keekeeke

Sub-Topic:
Content:
1. Kika ere onise.
2. Sise ere onise.
3. Ijiroro lori eko ti a ri ko ati eda inu itan.
WEEK 2

Theme: Litireso

Topic: Ere onise apileko kekere

Sub-Topic:
Content:
Sise ere onise keekeeke:
- Ti oluko fi inu ro.
- Ti o wa lati odo akekoo.
- Ti a ka lati inu iwe.
- To fa ogbon/eko yo.
WEEK 2

Theme: Litireso

Topic: Kika iwe ere onitan kekere

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ka iwe ere onitan kekere kan ni kilaasi.
2. Sise ere inu iwe ere onitan naa.
3. Atunso itan ere naa ni soki.
4. Ede itan ere ati iwa won.
5. Eko inu ere onitan naa.
WEEK 3

Theme: Litireso

Topic: Ewi

Sub-Topic:
Content:
1. Koko oro ajẹmọ́-oro to-n-lolawujo:
- Eto oro-aje
- Iselu
- Ewe iwoyi ati
idagbasoke awujo, abbl.
2. Aato ewi
3. Ona-ede ati isowolo ede.
WEEK 3

Theme: Litireso

Topic: Orin ibile to jemo ayéye

Sub-Topic:
Content:
1. Awon orin ibile to jemo ayéyeigbeyawo, ìkómojáde, oyejije, abbl.
2. Igbeyawo: E fun wa niyawowa...
Ìkómojáde: Omo la o fi gbejo eee... abbl
WEEK 3

Theme: Litireso

Topic: Kika iwe ere onitan kekere (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ka iwe ere onitan kekere kan ni kilaasi.
2. Sise ere inu iwe ere onitan naa.
3. Atunso itan ere naa ni soki.
4. Ede itan ere ati iwa won.
5. Eko inu ere onitan naa.
WEEK 4

Theme: Litireso

Topic: Aló apamo

Sub-Topic:
Content:
1. Aló apamo kii ni orin.
2. Maa n je ibeere ati ìdáhùn b.a. ki lo koja lójúde oba ti ko ki oba? = agbara ojo
3. Ma a n waye saaju aló onítan.
WEEK 4

Theme: Litireso

Topic: Akanlò ede ati owe

Sub-Topic:
Content:
1. Ìtẹ̀síwájú ninu ilo owe.2. Lilo akanlò ede.- Apeere akanlò ede atiitumo re.3. Bi a ti n lo o b.a: fonmu, forijalé agbon, bode pade, tateru nipaa abbl
WEEK 4

Theme: Litireso

Topic: Kika iwe ere onitan kekere (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ka iwe ere onitan kekere kan ni kilaasi.
2. Sise ere inu iwe ere onitan naa.
3. Atunso itan ere naa ni soki.
4. Ede itan ere ati iwa won.
5. Eko inu ere onitan naa.
WEEK 5

Theme: Litireso

Topic: Aló apamo (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Aló apamo kii ni orin.
2. Maa n je ibeere ati ìdáhùn b.a. ki lo koja lójúde oba ti ko ki oba? = agbara ojo
3. Ma a n waye saaju aló onítan.
WEEK 5

Theme: Litireso

Topic: Akanlò ede ati owe (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ìtẹ̀síwájú ninu ilo owe.2. Lilo akanlò ede.- Apeere akanlò ede atiitumo re.3. Bi a ti n lo o b.a: fonmu, forijalé agbon, bode pade, tateru nipaa abbl
WEEK 5

Theme: Litireso

Topic: Kika ewi kekere

Sub-Topic:
Content:
1. Kika ewi kekere
2. Ijiroro lori eko inu re
3. Alaye lori oro ti o ta koko
WEEK 6

Theme: Litireso

Topic: Owe

Sub-Topic:
Content:
1. Owe ati pataki re
2. Titumo owe ati lilo o b.a.:
- Esin iwaju ni teyin woo sáré.
- Ile oba to jo, ewa lo bu si i.
- Ateyin kọgbón a gétì aja, a ge e leti tan. O n fi abe pamo
- Oju awo ni awo fi n gba obe, abbl.
WEEK 6

Theme: Litireso

Topic: Ede Alonilahon

Sub-Topic:
Content:
1. Ohun ti ede alonilahan je.
2. Iwulo re. B.a.:a fi n ko pipeiro ede yorùbá.
3. Pe ipede alonilahon b.a.:
- Mo padaba, labà,aladaba n o falaba ladaba je.
- Mo ra dodo nidoo, mofowo dodo romo onídodoonidodo.
4. Ìdánrawò ninu sìso ipedealonilahon ni opolopo igba titiyoo fi da saka lenu won.
WEEK 6

Theme: Litireso

Topic: Kika ewi kekere (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Kika ewi kekere
2. Ijiroro lori eko inu re
3. Alaye lori oro ti o ta koko
WEEK 7

Theme: Litireso

Topic: Owe (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Owe ati pataki re
2. Titumo owe ati lilo o b.a.:
- Esin iwaju ni teyin woo sáré.
- Ile oba to jo, ewa lo bu si i.
- Ateyin kọgbón a gétì aja, a ge e leti tan. O n fi abe pamo
- Oju awo ni awo fi n gba obe, abbl.
WEEK 7

Theme: Litireso

Topic: Ede Alonilahon (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ohun ti ede alonilahan je.
2. Iwulo re. B.a.:a fi n ko pipeiro ede yorùbá.
3. Pe ipede alonilahon b.a.:
- Mo padaba, labà,aladaba n o falaba ladaba je.
- Mo ra dodo nidoo, mofowo dodo romo onídodoonidodo.
4. Ìdánrawò ninu sìso ipedealonilahon ni opolopo igba titiyoo fi da saka lenu won.
WEEK 7

Theme: Litireso

Topic: Itandowe (awon owe onitan)

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ni itandowe?
2. Orisirisi owe tio ni itan ninu bii:
- Ijapa ati igbin-alo ni ti ahun abo ni ti ana re;
- Oore nigun se to fipa lori, oore lakalamagbo se tofi yo gege, oore ni agbe kura se ti eni dudu fi di funfun.
WEEK 8

Theme: Litireso

Topic: Alo onítan ti ko lorin

Sub-Topic:
Content:
1. Alo onítan ti ko lorin b.a.
- Akùko ati kolokolo.
- Ijapá ati igbin
- Bi igun se pa lori, abbl.
2. Awon eko ti a ri fáyo ninu awon alo onítan ti ko lorin naa.
WEEK 8

Theme: Litireso

Topic: Kika Itan aroso keekeeke.

Sub-Topic:
Content:
1. Kika awon iwe itan arosokeekeeke.
2. So itan naa ni soki
3. Fa eko inu itan naa yo.
WEEK 8

Theme: Litireso

Topic: Itandowe (awon owe onitan) (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ni itandowe?
2. Orisirisi owe tio ni itan ninu bii:
- Ijapa ati igbin-alo ni ti ahun abo ni ti ana re;
- Oore nigun se to fipa lori, oore lakalamagbo se tofi yo gege, oore ni agbe kura se ti eni dudu fi di funfun.
WEEK 9

Theme: Litireso

Topic: Alo onítan ti ko lorin (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Alo onítan ti ko lorin b.a.
- Akùko ati kolokolo.
- Ijapá ati igbin
- Bi igun se pa lori, abbl.
2. Awon eko ti a ri fáyo ninu awon alo onítan ti ko lorin naa.
WEEK 9

Theme: Litireso

Topic: Kika Itan aroso keekeeke (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Kika awon iwe itan arosokeekeeke.
2. So itan naa ni soki
3. Fa eko inu itan naa yo.
WEEK 9

Theme: Litireso

Topic: Itandowe (awon owe onitan) (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ni itandowe?
2. Orisirisi owe tio ni itan ninu bii:
- Ijapa ati igbin-alo ni ti ahun abo ni ti ana re;
- Oore nigun se to fipa lori, oore lakalamagbo se tofi yo gege, oore ni agbe kura se ti eni dudu fi di funfun.

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

We provide educational resources/materials, curriculum guide, syllabus, scheme of work, lesson note & plan, waec, jamb, O-level & advance level GCE lessons/tutorial classes, on various topics, subjects, career, disciplines & department etc. for all the Class of Learners

THIRD TERM
BASIC 4 BASIC 5 BASIC 6
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 2

Theme: Asa

Topic: Iwa rere ati iwa buruku/ibi

Sub-Topic:
Content:
1. Apeere iwa rere b.a. aanu sise, ibowo-fagba, siso otito, ìfarada, abbl.
2. Awon iwakiwa ati ibi ti o wa ninu won.
3. Didekùn ohun ti o le ran iwakiwa lowo b.a.: igbo mimu, lilo oogun oloro, abbl.
4. Ife si orile-ede b.a.: didekun jija orile-ede lolè, didekun biba awon ohun amuluudun je.
5. “Eje si orile-ede mi”.
WEEK 2

Theme: Asa

Topic: Imototo ayika

Sub-Topic:
Content:
Itoju ile ati ayika: riro okoegbe ile ati ayika ile-eko;gbigba ayika ile ati ile eko,fifo ile.
WEEK 2

Theme: Asa

Topic: Imoose lati se àseyorí

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ni sise àseyorí.
2. Ki ni Imoose
3. Abuda àseyorí:
- Ise asekara/Aisemele
- Iforiti/ifarada
- Suuru
- Iwa pele/tutu
- Ìfarabalè
- Igboran
- Ìtẹríba, abbl
4. Awon akoni atijo ati tòde oni to ti se àseyorí nipa amulo awon abuda wonyi:
- Ajayi Crowther
- Hebert Macauly
- Obafemi Awolowo
- Ladoke Akintola
- Funmilayo Ransom Kuti
- Bolanle Awe
- Moremi
WEEK 3

Theme: Asa

Topic: Iwa rere ati iwa buruku/ibi (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Apeere iwa rere b.a. aanu sise, ibowo-fagba, siso otito, ìfarada, abbl.
2. Awon iwakiwa ati ibi ti o wa ninu won.
3. Didekùn ohun ti o le ran iwakiwa lowo b.a.: igbo mimu, lilo oogun oloro, abbl.
4. Ife si orile-ede b.a.: didekun jija orile-ede lolè, didekun biba awon ohun amuluudun je.
5. “Eje si orile-ede mi”.
WEEK 3

Theme: Asa

Topic: Orisiirisii oruko yorùba

Sub-Topic:
Content:
1. Pataki oruko ni ile yorùba.
2. Orisiirisii oruko yorùba atialaye nipa idi ti won fi n je e.Apeere:
● Oruko abiso
- Oluyemisi
- Kayode
● Oruko amutorunwa
- Tayé, Kehinde
- Idòwú, Igẹ, Àìna...
● Oriki
- Anike
- Àkano
- Ajike
- Akanmú
● Inagije
- Owódunni
- Olowolayemo
- Jegede
- Apayinoge
- Aguntasoolo
● Oruko idile
- Ogundare
- Ayandele
- Oosagbemi
- Efunsetan
WEEK 3

Theme: Asa

Topic: Asìlò oogun

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ni asìlò oogun?
- Lilo oogun koja bi o ti ye
- Lilo oogun ti ko ye ki a lo ni mimoomo tabi aimoomo
2. Anfaani oogun lilo fun imularada bi a ba lo o bi o ti to
3. Ewu asìlò oogun:
- Iku
- Ìpalára, aisan
- Didi alaabo ara
- Ki lilo oogun di bárakú.
4. Die ninu ona ti a le fi dekun ṣíṣí oogun lo.
- Yiye oogun ti a ba fe lo wo daradara fun déètì ti yoo wulo da
- Ikora eni nijanu
- Yiyago fun egbekegbe
- Gbigbe oogun si bi ti owo omode ko to.
WEEK 4

Theme: Asa

Topic: Ise amuse

Sub-Topic:
Content:
1. Ise yoruba.
2. Bi a se n kini lenu ise b.a.
Alaro = Aredu, arepon,
Akope = igba a ro o,
onídiri = oju gbooro o.;
Agbe = aroko bodunde, abbl.
WEEK 4

Theme: Asa

Topic: Orisiirisii oruko yorùba (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Pataki oruko ni ile yorùba.
2. Orisiirisii oruko yorùba atialaye nipa idi ti won fi n je e.Apeere:
● Oruko abiso
- Oluyemisi
- Kayode
● Oruko amutorunwa
- Tayé, Kehinde
- Idòwú, Igẹ, Àìna...
● Oriki
- Anike
- Àkano
- Ajike
- Akanmú
● Inagije
- Owódunni
- Olowolayemo
- Jegede
- Apayinoge
- Aguntasoolo
● Oruko idile
- Ogundare
- Ayandele
- Oosagbemi
- Efunsetan
WEEK 4

Theme: Asa

Topic: Awon ona ibara-eni-soro ibile ati ode oni

Sub-Topic:
Content:
1. Ohun ti ibara-eni-soro je.
2. Ilo eya ara fun biba ara-enisoro.
3. Awon ohun elo àfojúrí fun biba ara-eni-soro.
4. Dida awon ohun elo olohun mo
5. Idámo ati iyato laarin ohun ìbánisọ̀rọ̀ laye atijo ati lode oni.
WEEK 5

Theme: Asa

Topic: Ise amuse (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ise yoruba.
2. Bi a se n kini lenu ise b.a.
Alaro = Aredu, arepon,
Akope = igba a ro o,
onídiri = oju gbooro o.;
Agbe = aroko bodunde, abbl.
WEEK 5

Theme: Asa

Topic: Oruko oba alaye ati ilu won

Sub-Topic:
Content:
Oruko oye awon oba alayeile yorùba ati ilu won b.a.Ooni Ile-ife, Alaafin-Oyo.Ogiyan-Ejigbo
WEEK 5

Theme: Asa

Topic: Ona irinàjo latijo ati lode oni.

Sub-Topic:
Content:
1. Orisiirisii ohun irinse laye atijo b.a ese, esin, oko ojuomi.
2. Ohun irinse lode oni b.a:
- Oko
- Ile
- Oju irin
- Òfurufú
- Oju-omi
- Keke
- Alupupu (òkada)
3. Awon anfaani to wa ninu ona irin ajo atijo ati tòde oni b.a. kii saaba si ewu ijamba lona ni atijo, bee ni ohun irinse won ko ni eefin to n ba aféfé je. Anfaani ohun irinse ode oni:
- O ya kia kia
- O roni lorun ju ti atijo lo
Aleebu ohun irinse latijo b.a.
- Ewu olosa, akonileru ati eranko buburú. Aleebu ti ode oni
- Ewu ijamba
- Ewu danadana
- Eefin re n ba aféfé je, abbl.
4. Awon arin-rin-ajo latijo maa n kowoo rin, won le gba jagunjagun lati tele won lo irin ajo nitori awon danadana ati amunileru.
WEEK 6

Theme: Asa

Topic: Ounje

Sub-Topic:
Content:
1. Orisiirisii ounje ti awon yoruba n je.
2. Isori ounje pelu apeere b.a. Afaralokun = Amala, eba, iyan, eko, abbl Amadan:
eyin, eja, eran, abbl.
Asemiro = awon eso ounje oloraa: epo, oróro, bota, ora-eran, abbl.
3. Ounje ipanu: epa, guguru, dodo, ipekere, abbl.
WEEK 6

Theme: Asa

Topic: Ise Amuse

Sub-Topic:
Content:
1. Ise yorùba
2. Bi a se n ki ni lenu ise b.a.aAlaro: aredu, arepon o;
- Akope: igba a ro o;
- Onidiri: oju gbooro o;
- Agbe: Aroko-bodunde,abbl
WEEK 6

Theme: Asa

Topic: Oge sise ati imúra ni ile Yorubá

Sub-Topic:
Content:
1. Oge sise-eyin pipa, ara sise/finfin, tiroo lilé, laali lile, eti lilu, irun-gige/kiko abbl.
2. Imúra aso wiwo to wuyì/tabuku eniyan, bata wiwo, bata wiwo, bebe idi, ileke lilo, abbl.
WEEK 7

Theme: Asa

Topic: Ounje (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Orisiirisii ounje ti awon yoruba n je.
2. Isori ounje pelu apeere b.a. Afaralokun = Amala, eba, iyan, eko, abbl Amadan:
eyin, eja, eran, abbl.
Asemiro = awon eso ounje oloraa: epo, oróro, bota, ora-eran, abbl.
3. Ounje ipanu: epa, guguru, dodo, ipekere, abbl.
WEEK 7

Theme: Asa

Topic: Ise Amuse (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ise yorùba
2. Bi a se n ki ni lenu ise b.a.aAlaro: aredu, arepon o;
- Akope: igba a ro o;
- Onidiri: oju gbooro o;
- Agbe: Aroko-bodunde,abbl
WEEK 7

Theme:

Topic:

Sub-Topic:
Content:

WEEK 8

Theme: Asa

Topic: Aso wiwo

Sub-Topic:
Content:
1. Orisiirisii aso ti a n wo ni ile Yoruba fun oniruuru igba bii, ooru, aso ise, iwole, fun tokunrin, tobinrin.
2. Orisiirisii aso igbalode b.a. seti, tirosa, suweta, gaun, sikeeti, kóòtù, abbl.
3. Anfaani ati aleebu aso igbalode
WEEK 8

Theme: Asa

Topic: Igbeyawo ni ilana ti ibileyorùba

Sub-Topic:
Content:
Ilana asà igbeyawo ibile
● Eto ifojusode,
ìjóhen/isihun, itoro
● Idana
● Igbeyawo
● Ikora eni ni ijanu nipaibalopo saaju igbeyawo.
WEEK 8

Theme:

Topic:

Sub-Topic:
Content:

WEEK 9

Theme: Asa

Topic: Aso wiwo (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Orisiirisii aso ti a n wo ni ile Yoruba fun oniruuru igba bii, ooru, aso ise, iwole, fun tokunrin, tobinrin.
2. Orisiirisii aso igbalode b.a. seti, tirosa, suweta, gaun, sikeeti, kóòtù, abbl.
3. Anfaani ati aleebu aso igbalode
WEEK 9

Theme: Asa

Topic: Ohun elo ise/irinse

Sub-Topic:
Content:
1. Ise yorubá ati ohun elo/irinsewon b.a.:
- Agbe-oko,ada,abbl
- Ode – ìbon, ota, etu,abbl.
- Akope – igba,akèrèngbè, abbl.
- Agbe – igi, ada, obe,abbl.
2. Ki akekoo so ise miiran atiirinse won.
3. Kiko akekoo lo si ibi ti won tin se ise yii lati ri irin ise sii.
WEEK 9

Theme:

Topic:

Sub-Topic:
Content:

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

We provide educational resources/materials, curriculum guide, syllabus, scheme of work, lesson note & plan, waec, jamb, O-level & advance level GCE lessons/tutorial classes, on various topics, subjects, career, disciplines & department etc. for all the Class of Learners

Free Will Donation

We know times are tough right now, but if you could donate and support us, be rest assured that your great contributions are immensely appreciated and will be for the progress of our work to help us pay for the server cost, domain renewal, and other maintenance costs of the site. Nothing is too small; nothing is too little.

Account Details

BANK: UNITED BANK FOR AFRICA PLC

ACCOUNT NAME: OFAGBE GODSPOWER GEORGE

ACCOUNT NUMBER: 2250582550

SWIFT CODE: UNAFNGLA

ACCOUNT TYPE: SAVINGS

CURRENCY: DOLLAR (USD) ACCOUNT

ADDRESS: 1. M. Aruna Close, Ughelli, Delta State, Nigeria

PHONE: +234805 5084784, +234803 5586470

BANK: UNITED BANK FOR AFRICA Plc (UBA)

ACCOUNT NAME: OFAGBE GODSPOWER GEORGE

ACCOUNT NUMBER: 2042116266

SORT CODE: 033243371

ACCOUNT TYPE: SAVINGS

CURRENCY: NAIRA ACCOUNT

ADDRESS: 1. M. Aruna Close, Ughelli, Delta State, Nigeria

PHONE: +234805 5084784, +234803 5586470

Your active support gives strength to our Team and inspires to work. Each donated dollar is not only money for us, but it is also the confidence that you really need our project!
AseiClass is a non-profit project that exists at its founders' expense, it will be difficult to achieve our goals without your help.
Please consider making a donation.
Thank you.

AseiClass Team

We provide educational resources/materials, curriculum guide, syllabus, scheme of work, lesson note & plan, waec, jamb, O-level & advance level GCE lessons/tutorial classes, on various topics, subjects, career, disciplines & department etc. for all the Class of Learners

Facts about Teachers

● ● ● Teachers Are Great No Controversy.

● ● ● Teachers are like candles, they burn themselves to light others.

● ● ● Teachers don't teach for the money.

● ● ● Every great mind was once taught by some brilliant teachers.

● ● ● Teachers are the second parents we have.

● ● ● If you can write your name, thank your teacher.

Teaching slogans

● ● ● Until the learner learns the teacher has not taught.

● ● ● I hear and forget, I see and remember, I do and know.

● ● ● The good teacher explains. The superior teacher demonstrates. The great teacher inspires.